Fílípì 4:6

Fílípì 4:6

Ẹ má ṣe ṣe àníyàn ohunkóhun; ṣùgbọ́n nínú ohun gbogbo, nípa àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ pẹ̀lú ìdúpẹ́, ẹ máa fi ìbéèrè yín hàn fún Ọlọ́run. English Translation: “Be careful for nothing; but in every thing by prayer and supplication with thanksgiving let your requests be made...
Isaiah 9:6

Isaiah 9:6

  Nítorí a bí ọmọ kan fún wa,     a fi ọmọkùnrin kan fún wa, ìjọba yóò sì wà ní èjìká rẹ̀.     A ó sì máa pè é ní: Ìyanu Olùdámọ̀ràn, Ọlọ́run Alágbára     Baba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà.   English Translation: “For unto us a child is born, unto us...
Lúùkù 6:38

Lúùkù 6:38

Ẹ fi fún ni, a ó sì fi fún yín; òṣùwọ̀n dáradára, àkìmọ́lẹ̀, àti àmìpọ̀, àkúnwọ́sílẹ̀, ni a ó wọ́n si àyà yín: nítorí òṣùwọ̀n náà tí ẹ̀yin fi wọ́n, òun ni a ó padà fi wọ́n fún yín.   English Translation: “Give, and it shall be given unto you; good measure,...
Orin Dáfídí 1:2

Orin Dáfídí 1:2

  Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú rẹ̀ wà nínú òfin Olúwa     àti nínú òfin rẹ̀ ni ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán àti òru.   English Translation: “But his delight is in the law of the LORD; and in his law doth he meditate day and night.”_ Psalms.1:2 Explanation: This...