Bible Verses
Ni àtètèkóse Olórun dá òrun àti aiyé English Translation: “In the beginning God created the heavens and the earth”-Genesis. 1:1 Explanation: This iconic verse from the book of Genesis serves as the opening line of the Bible and the...
Bible Verses
In all thy ways acknowledge him, and he shall direct thy paths. Yoruba Translation: Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ. Explanation: In Proverbs 3:6, the wise king Solomon offers a life-changing principle: when we...
Bible Verses
Rejoice in the Lord always: and again I say, Rejoice. Yoruba Translation: “Ẹ máa yọ̀ nínú Olúwa nígbà gbogbo: mo sì tún wí pé. Ẹ máa yọ̀”_ Fílípì.4:4 Explanation: This powerful verse from Paul’s letter to the Philippians urges...
Bible Verses
Ẹ má ṣe ṣe àníyàn ohunkóhun; ṣùgbọ́n nínú ohun gbogbo, nípa àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ pẹ̀lú ìdúpẹ́, ẹ máa fi ìbéèrè yín hàn fún Ọlọ́run. English Translation: “Be careful for nothing; but in every thing by prayer and supplication with thanksgiving let your requests be made...
Bible Verses
Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, a fi ọmọkùnrin kan fún wa, ìjọba yóò sì wà ní èjìká rẹ̀. A ó sì máa pè é ní: Ìyanu Olùdámọ̀ràn, Ọlọ́run Alágbára Baba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà. English Translation: “For unto us a child is born, unto us...
Bible Verses
Ẹ fi fún ni, a ó sì fi fún yín; òṣùwọ̀n dáradára, àkìmọ́lẹ̀, àti àmìpọ̀, àkúnwọ́sílẹ̀, ni a ó wọ́n si àyà yín: nítorí òṣùwọ̀n náà tí ẹ̀yin fi wọ́n, òun ni a ó padà fi wọ́n fún yín. English Translation: “Give, and it shall be given unto you; good measure,...