Bible Verses
Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú rẹ̀ wà nínú òfin Olúwa àti nínú òfin rẹ̀ ni ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán àti òru. English Translation: “But his delight is in the law of the LORD; and in his law doth he meditate day and night.”_ Psalms.1:2 Explanation: This...